Ṣọlá Kòsọ́kọ́: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
New Page Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù |
(Kò ní yàtọ̀) |
Àtúnyẹ̀wò ní 13:03, 26 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
Ṣọlá Kòsọ́kọ́-Abíná (tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù Kínní ọdún born 1976), jẹ́ oṣèrébìnrin àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jé ọmọ bíbí àgbà òṣèrè Jídé Kòsọ́kọ́. [1]
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "Sola Kosoko Biography, Age, Marriage, Career, Movies, Net worth, Twitter". Informationcradle. 2017-07-15. Retrieved 2019-10-26.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Ṣọlá_Kòsọ́kọ́&oldid=525286"